Yoruba Nation Anthem...
Ìṣe wa fún ilé wa
Fún ilé ibi wa
Ká gbé ga, ká gbé ga
Ká gbé ga f'aiye ri
Ìgbàgbọ́ wa ni pé
B'a ti b'ẹrú, là b'ọmọ
K'á ṣiṣẹ́, k'á ṣiṣẹ́
K'á ṣíṣe, f'aiye ri.
Iṣọ̀kan àti Ominira
Ní k'ẹ jẹ́ ká máa lepa
'Tesiwaju, f' ọ̀pọ̀ ire
At'oun to dára
Ọmọ. Oodua dide
Bọ́ s'ipo ẹtọ́ rẹ́
Ìwọ ni imọ́lẹ̀
Ògo Adúláwọ..
Crystal Media.
Download Oduduwa National Anthem here
https://drive.google.com/file/d/11U2LGKvsjQ2UFV5Cv_I86HRom1PzUDii/view?usp=drivesdk
Comments
Post a Comment