Skip to main content

Posts

Showing posts from May, 2021

YORUBA NATION ANTHEM

Yoruba Nation Anthem... Ìṣe wa fún ilé wa Fún ilé ibi wa Ká gbé ga, ká gbé ga Ká gbé ga f'aiye ri Ìgbàgbọ́ wa ni pé B'a ti b'ẹrú, là b'ọmọ K'á ṣiṣẹ́, k'á ṣiṣẹ́ K'á ṣíṣe, f'aiye ri. Iṣọ̀kan àti Ominira Ní k'ẹ jẹ́ ká máa lepa 'Tesiwaju, f' ọ̀pọ̀ ire At'oun to dára Ọmọ. Oodua dide Bọ́ s'ipo ẹtọ́ rẹ́ Ìwọ ni imọ́lẹ̀ Ògo Adúláwọ.. Crystal Media. Download Oduduwa National Anthem here https://drive.google.com/file/d/11U2LGKvsjQ2UFV5Cv_I86HRom1PzUDii/view?usp=drivesdk