Download the Oduduwa Anthem here. https://drive.google.com/file/d/11U2LGKvsjQ2UFV5Cv_I86HRom1PzUDii/view?usp=drivesdk Yoruba Nation National Anthem is in Yoruba. Ìṣe wa fún ilé wa Fún ilé ibi wa Ká gbé ga, ká gbé ga Ká gbé ga f'aiye ri Ìgbàgbọ́ wa ni pé B'a ti b'ẹrú, là b'ọmọ K'á ṣiṣẹ́, k'á ṣiṣẹ́ K'á ṣíṣe, f'aiye ri. Iṣọ̀kan àti Ominira Ní k'ẹ jẹ́ ká máa lepa 'Tesiwaju, f' ọ̀pọ̀ ire At'oun to dára Ọmọ. Oodua dide Bọ́ s'ipo ẹtọ́ rẹ́ Ìwọ ni imọ́lẹ̀ Ògo Adúláwọ.. Start Learn it now Oduduwa most go
On our website, we value transparency.. we let you know how it happened and give you exact information without compromising our value.
Comments
Post a Comment